IIMMOOLLEE TTIITTUUNN 1 AAPPAA KKIINNNNII tata ta Iwe kika fun awoýn agba peýlu ilana ti eýkoý Bibeli. Lati O:woý: Dr. Kehinde O. Anifowoshe Peýlu Oluranloýwoý re: Dr. Robert F. Rice Atunyeýwo yi wa lati oýwoý Pastor Ademola Abimbola Bi a sýe n koý leýta kekere: a t o w i n r e s u l j k m f g b p Akiyesi Pataki Lati koýni loýna ti o keýseý jari a gboýdoý teýle Ilana Ikoýni. Ko sýeesýe lati koý eniyan ni eýkoý inu iwe yii daadaa lai jeý wi pe eniyan teýle awoýn igbeseý marun-un geýgeý bi a seý toýka reý sinu Ilana Ikoýni. (4-15) ati ni oju iwe (20-21). Awoýn iwe meji yii Imoýleý Titun ati Ilana Ikoýni ni a le ri ni ile isýeý: Eýýkoý Agba, P. M. B. 5113, Ibadan, Nigeria Ati Heirs of God Christian Ministry, P.O. Box 6887, Agodi, Ibadan. Atunyewý o silebu fun apa kinni: Fun akeýkoýoý lati tunyeýwo (sýe atunyeýwo) nigba gbogbo. a à o i e u ta tà to ti te tu wa wà wo wi we wu na nà no ni ne nu ra rà ro ri re ru sa sà so si se su la là lo li le lu ka kà ko ki ke ku ma mà mo mi me mu fa fà fo fi fe fu gba gbà gbo gbi gbe gbu pa pà po pi pe pu ba bà bo bi be bu LEýTA aA bB dD eE eýEý fF gG gbGb hH iI jJ kK lL mM nN oO oýO: pP rR sS sýS: tT uU wW yY ADURA OLUWA Baba wa ti n beý li oýrun, oýwoý ni forukoý reý. Ki ijoýba reý de. Ifeý tireý ni ki a sýe laye, bi woýn ti n sýe loýrun. Fun wa lounjeý oojoý wa lonii. Dari eýsýeý wa ji wa, bi a ti n dari ji awoný to sýe wa. Ma fa wa sinu idanwo, sýugboýn gba wa loýwoý bilisi: Nitori ijoýba ni tireý, Agbara ni tireý, Ogo ni tireý lailai. Amin. Awoýn iwe meji yii Imoýleý Titun ati Ilana Ikoýni ni a le ri ni ile isýeý: Eko-Agba, P.M.B. 5113, Ibadan, Nigeria Ati Heirs of God Christian Ministry, P.O. Box 6887, Agodi, Ibadan. Literacy International 1800 S. Jackson Avenue Tulsa, OK 74107, USA ([email protected]) Imóýlèý Titun Apa Kinni-in - E:koý 1-30 Lati oýwoý: Dr. Kehinde O. Anifowosýhe Peýlu oluranloýwoý rèý: Dr. Robert F. Rice E:ni ti o sýe atunyeýwo yi ni: Pastor Ademola F. Abimbola Awoýn Ayàwòrán: B. Okosi & T. Yekeen Ìfihàn leýta titun nìwoýn yi: 1. a, o, t, w 11. -- 21. p 2. i, oý 12. j, J, O, O: 22. -- 3. n 13. eý 23. b, B, E: 4. -- 14. k 24. 5. r 15. -- 25. sý 6. e 16. m 26. Leýta Nla 7. s 17. f 27. 8. u 18. gb 28. g 9. -- 19. -- 29. d 10. l 20. y 30. 2009 edition: Copyright © 2009 Literacy International Previous edition: Joint copyright © 1991 Literacy International and the Adult Education Department of the Nigerian Baptist Convention Copyright ownership: All rights reserved. Reproduction of IMO:LE: TITUN in whole or in part, without permission of Literacy International ([email protected]) is strictly prohibited. O:RO: IS:AAJU (AKO:SO:) Àgbàlagbà ti o ba mòýwéékoý ti o si móýwéékà wulo ni ile Ol: oýrun. Iru àgbàlagbà beýeý yoo le moý itumoý awoýn ofin orileý-ede rèý, yoo si le pa awoýn ofin orileý-ede reý moý. Peýlu agbara lati kàwé ati afikun imoý, o le ran orileý-ede ati awoýn asýaaju reý loýwoý. Àgbàlagbà ti o ba mòýwéékà ni lati tun lagbara ninu igbagboý nipa kika oýroý O:loýrun. O tun le jeý oluranloýwoý fun Oniwaasu reý ati awoýn oýmo-ijoý nigba ti o ba n ka oýroý O:loýrun funrare.ý O:roý O:loýrun soý wi pe “Nitori naa mo gba yin niyanju sýaaju ohun gbogbo, pe ki a maa beýbeý, ki a maa gbadura, ki a maa sìpèý, ati ki a maa dúpéý nitori gbogbo eniyan; fun awoýn oýba, ati gbogbo awoýn ti o wa ni ipo giga; ki a le maa lo aye wa ni idakeýjeýeý ati pèýléý ninu gbogbo iwa-bi-O:loýrun ati ìwà àgbà”. Gbogbo onigbagboý gboýdoý jeý eýni ti o maa n× ka Bibeli déédé. E: jeý ki a ran ara wa loýwoý lati le kàwé ati le kòýwé. Onigbagboý ti o ba mòýóýkoý-mòýóýkà gboýdoý koý, o kere patapata, eýnikan ti ko le kàwé. “Ki eýni ti o moýweý koý eýlomiran” nipa sýisýe beýeý a o ran gbogbo eniyan loýwoý lati mòýwéý ka. Imóýlèý Titun wa fun bi a sýe n koý onígbàgbóý bi o sýe le ka Bibeli rèý. Awoýn iwe méjì tabi méýta wa ti apapoý èýkóý woýn jeý oýgoýta (72). Olukoý ni lati teýle iwe Ìlana Ìkoýni ki o ba le ni oye awoýn eýkoý inu iwe naa. Awoýn léýtà nla ni a fi sýaaju ninu eýkoý keýrinlelogun (26). Awoýn òýýròý inu Bibeli bèýrèýý peýlu èýkóý kejila, ti o fi orukoý JESU han. E:seý Bibeli kan wa fun olukoý lati ka leýhin eýkoý koýoýkan. Noýnba (iye), Isýiro, ati leýta kikoý ni a n kòý ninu awoýn eýkoý keýtaleloýgboýn (33) ati eýkoý keýrinleloýgboýn (34). Awoýn eýkoý nipa eto ilera ati isýeý agbeý wa ni eýkoý karudinlogoji (35) titi de eýkoý keýrindinlaadoýta (46). Awoýn itan lati inu Bibeli ti a ti ke kuru ni o wa ninu awoýn eýkoý karundinlogoji (47) titi de eýkoý oýgoýta (72). 2 PATAKI: Ki o to le koý eniyan ni àkóýyege, o ni lati tèýlé iwe ètò Ìlana Ìkoýni. Eniyan ti yoo koý awoýn eýkoý woýnyi ko le sýe e loýna eýtoý bi ko ba farabaleý ka ati sýe “ohun ti olukoý soý” ninu iwe Ìlana Ìkoýni. Olùkóý naa ni lati kaa, o si ni lati gbáradì fun ati koýni ni eýkoý, ki o to maa koý awoýn akeýkoýoý reý. Ki o koý eniyan geýgeý bi “Ìgbésèý ý marun-un” ati awoýn ilana miran ti o wa ninu iwe Ìlana Ìkoýni. Àwoýýn òfin fun ìkóýni ti o kéýseýjárí: 1. Sòýýròý pèýléýpèýléý. Ni òýyàyà ki o si ni iteýriba. 2. Sòýròý niwòýn-tun-woýnsi. 3. Ri i wi pe o n gba awoýn akeýkoýoý reý níyànjú nigba gbogbo. Yin in nigba gbogbo fun agbara reý. Ma sýe bínú nitori asýisýe. 4. Ma sýe soý wi pe “Beýeýkoý, o kuna. S:e o ò moý eyi ni?” 5. Ni ìrèýlèý, fi oýla fun akeýkoýoý reý. Ka a kun eýgbeý eý reý; ma sýe ro ara re si oýga. 6. Ma sýe fi awoýn asýisýe awoýn akeýkoýoý reýrin-in, ma si sýe gba ki awoýn eýlomiran fi woýn reýrin-in. 7. Feýràn akeýkoýoý reý ki o si soý fun un wi pe o le moýwe kiakia. RANTI: Ko sýe e sýe lati koý eniyan ni eýkoý inu iwe yii daadaa lai jeý wi pe eniyan teýle awoýn “Igbeseý marun-un.” Ki o to le koý eniyan daadaa, olukoý gboýdoý koý awoýn “Igbeseý marun-un” fun kikoý eýkoý. Wo ètò Ìlana Ìkoýni peýlu. Awoýn eýkoý inu iwe akoýkoý ni a sýe kikoýni peýlu awoýn “Igbeseý marun-un” lai toý ilana miran. Gbadura -- S:isýe -- Waasu 3 ÌLANA FUN KIKO NI NI EKO BI A S:E N KO:NI ATI BI A S:E N JE:RI A. BI A S:E N JE:RI I. Igbaradi lati jeýri II. Ohun ti onigbagboý wi B. BI A S:E N KO:NI I. Mímúrasíleý II. Igbaradi fun iwe-kika III. Ohun ti olukoý soý. IV. Bi a sýe n× kóýni ni iwe-kikoý V. Isýéý-ilé VI. Leýta nla-nla IPARI A. BI A S:E N JE:RI I. Igbaradi ati Jeýri Ohun ti o sýe pataki nipa ihinrere eýkoý agba ni lati koý akeýkoý reý bi a ti nka bible ki a le ti ipaseý reý mu ijeýri ninu ijoý gbooro sii. Olukoý gboýdoý mura sileý fun anfaani ti o le ni lati jeýri ni akoko eýkoý kooý ký an. Bi o sýe n ran akeýkoý reý loýwoý lati kawe, o le sýe awoýn nnkan eými. Olukoý gboýdoý nifeý akeýkoý. Bibeýreý ati pipari eýkoý peýlu oýroý O:loýrun ati adura le sýileýkun ijeýri. Olukoý ti o ba fi ara reý jin yoo pateýmoý fun eýkoý reý gbogbo peýlu adura ki o to beýreý peýlu akeýkoý. Ijeýri olukoý leýyin eýkoý koýoýkan sýe pataki fun iru eýkoý beýeý. E:seý Bibeli wa ni oju iwe keji eýkoý koýoýkan. Olukoý le ka eýseý Bibeli fun akeýkoý leýyin eýkoý koýoýkan tabi ki o ka eýseý Bibeli miran lati inu oýkan ninu awoýn ihinrere. Beýreý lati eýkoý kejila ni ibi ti o fi orukoý Jesu han ati ninu awoýn eýkoý ti o teýle ni a gbarale Bibeli, olukoý gboýdoý sýetan nigba kugba lati gbe Jesu ga ki akeýkoý lee ri ki o si gba A gboý. Jesu soýý pe “Bi a ba gbemi soke (Lori igi agbelebu) emi yoo fa 4 gbogbo eniyan soýdoý emi tikalara mi”. Kikoýni laisi ijeýri ko kun oju osunwoýn. Ijeýri laisi isýeý, ni oýpoýloýpoý igba yoo kuna lati mu iyipada oýkan wa Sugboýn adura, ifeý si isýeý sisýe ati ijeýri, awoýn meýteýeýta yii yoo fun wa ni àyè lati jèrè oýkan oýpoýloýpoý fun Kristi. Lati ibeýreý eýkoý, ran akeýkoý loýwoý lati wa ni ìdèýra ati ìròýrùn. Nigba naa ni yoo farabaleý lati gboý ijeýri ti olukoý yoo jeý leýyin eýkoý. Lati fi ihinrere ni eýkoý han, awoýn ilana yii yoo wulo. II. Ohun Ti Onigbagboý Wi Bi o ba koýni peýlu adura ati ifeý Kristi akeýkoý yoo maa bi ara reý ni ibeere yi lóókan aya reý: “Eesýe ti olukoý mi fi dara bayi? Eesýe ti o fi ni ifeý si mi to yii?” Olukoý yoo beere ibeere yi leýyin eýkoý akoýkoý “N jeý o moý idi ti awa onigbagboý n fi n koý eniyan bi a sýe kawe?” Olukoý soý pe “A n se eyii nitori Jesu feý ki a sýe beýeý. Jesu ni asiwaju wa oninu-ire ti o koý gbe laye. O wo alaisan san, O boý awoýn ti ebi n× pa, o la oju afoýju ... sýugboýn ju gbogbo eyi loý, o feý mi to beý geýeý ti o fi jiya ti o si ku fun eýsýeý mi ati tireý peýlu. Jesu ku geýgeý bi etutu O:loýrun fun gbogbo eniyan. Leýyin naa, O:loýrun ji Jesu dide kuro ninu oku, o si wa peýlu O:loýrun Baba loke oýrun. O lee dari awoýn eýseý wa jin wa ki o si fi alaafia oýkan fun wa...... Mo feý ki o mo-ýoýn, ki o si moý bi aa ti ka itan Reý ninu Bibeli. Jesu ni olugbala mi, o si lee jeý olugbala reý peýlu.” Nipa kikoýni peýlu ifeý n× wa aye lati kóý akeýkoýoý nipa Kristi. Jijeý oýreý si akeýkoýo reý, ki o ba lee fokan tan oý, yoo sýi ileýkun oýreý laarin yin. O lee jeý oýna si ijeýwoý Kristi peýlu. Leýyin kikoý eýkoý keji, peýlu iyin ati iwuri, o sýe tan fun ijeýri eýleýeýkeji. Bi ó ba léè ka dipo ki o maa soýoý lený u lasan, o soý bayii: “Mo ti soý fun oý nipa agbayanu ifeý Jesu, eýniti o ku fun wa ti o si wa laaye nisisiyii fun wa. E: jeý ki n× ka itan iyanu kan fun yin lati inu Bibeli. Bi oò ba lee kawe, afoýju ni oý. S:ugboýn bi o ba ti pari eýkoý yi, oó léè ka itan yi funra-reý. Itan yii ni itan oýkunrin kan ti a bi ni afoýju.” (Johanu 9:1-7, 35-41) Ijeýri olukoý leýyin eýkoý koýoýkan ni o sýe pataki juloý ninu eýkoý kikoý fun ijeýri reý. Olukoý léè ka eýseý Bibeli fun awoýn akeýkoý leýyin eýkoý koýoýkan. O si lee ka ninu ihinrere miran tabi ibomiran ninu Bibeli. 5 Dahun awoýn ibeere iyanu ti awoýn akeýkoý lee beere. Fetisileý fun E:mi Mimoý. E:niti o lee dari reý lati soý ohun ti o yeý lati soý ohun ti o si lee ran oý loýwoý lati maa soý ohun ti ko yee. B. BI A SE N KO:NI I. Mímúrasíleý Ki o to maa koý akeýkoý reý, soý fun-un pe iwoý feý ki oun naa koý eýnikan ni mi-moý-oýn-koý ati mi-moý-oýn-ka, leýyin igba ti akeýkoý naa ba ti moý iwe ka tan. Geýgeý bi akeýkoý reý sýe ri iranloýwoý gba ni òýfeý, beýeý naa ni oun naa se gboýdoý ni ayoý lati ran eýlomiran loýwoý lati lee kawe. Bi a sýe n koý agbalagba yatoý si bi a sýe n koý awoýn oýmoýdé. Agbalagba wa lati keýkoý nitori pe o ti oýkan reý wa ni. A ko fi agbara mu-un. Ò:pòýloýpoý agbalagba ni won ro wi pe awoýn ko le mòýwé, ti woýn si nberu wipe awoýn yoo kuna. Sugboýn saa, awoýn agbalagba fe lati tete ko eko. Nitori naa, akeýkoýoý agba yoo beere lati eýkoý kinni-in. A ko feý sýeý akeýkoýoý wa. A feý ki o tun pada wa lati wa maa koý eýkoý si. Nitori naa, maa teýle awoýn ilana woýnyi. 1. Maa soýroý peýleý peýleý. Jeý Oníteýríba. 2. Maa fun akeýkoýoý reý ni igboya igba gbogbo. Ma sýe gbagbe lati maa yin fun igbiyanju re. Masýe jeý ki inu bi oý bi akeýkoýoýreý ba sýe àsìsé. 3. Jeý onírèýlèý, maa bòýwòý fun akeýkoý rèý. Mu akeýkoýoý reý geýgeý bi ara reý, masýe sýebi oýga fun akeýkoýoý reý. 4. Ma maa fi akeýkoý reý reýrin tabi ki o jeý ki eýlomiran fi woýn reýrin. Ma sýe kan akeýkoýoý reý lojù, mà sýe faa seýyin. 5. Feýran awoýn akeýkoýoý, ki o si maa fun won ni igboya pe woýn le moý-oýn koý, moý-oýn ka. Je ý ki eýkoý naa larinrin. 6. Ti o ko ba le koni, wa eýlomiran lati ran oý loýwoý, tabi sýe eto lati koý awoýn akeýkoýoý ni igba miran. BI A S:E NÁKO:NI, RANTI AWO:N KOKO WO:NYI: 1. Sòýròý ni wòýnba sóýkí. 6